ÌRÒYÌN YÀJÓYÀÓ
Trending

Abiodun Akinlade Fi Keke,Okada,Taya Okada ati firigi pelu ero Ata ati Genereto seto ironilagbara fawon Olugbe Guusu Yewa/Ipokia

Onorebu Abiodun Akinlade to n soju Guusu Yewa/Ipokia nile igbimo asofin Kekere nilu Abuja ti seto ironilagbara fawon Olugbe Guusu Yewa/ Ipokia to lo soju fun nile lgbimo asofin nilu Abuja.

Ojo kokondinlogun osu kewa odun egbaa odun ole merinlelogun yi ni Eto ironilagbara na waye ninu ogba Ile Iwe aladani ti The Gem International School,to wa nilu owode Yewa ni ijoba Ibile Guusu Yewa ni lpinle Ogun.


Akinlade fun awon eeyan ni Keke afesewa, Okada ati firigi pelu ero Ata .

Awon nnkan mii ti won tun fawon eeyan ni ero Amunawa kekere ati nla pelu Masinni iranso.
Bakan naa ni won tun fawon eeyan lowo.
Awon CDCs naa tun wa Lara awon ti won janfaani ninu Eto ironilagbara naa.

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button