ÈTÒ ÀÀBÒ
-
Komisana olopa Bode Ojajuni sabewo si idiroko,ilaro o si ro won lati tunbo maa gbà àlaafia laaye.
CP BODE OJAJUNI to je komisana olopa ipinle ogun ti gbe abewo re de idiroko ati ilu ilaro tiise olu…
Read More » -
Ajosepo to danmoran to wa laarin awa eleto aabo nipinle ogun lo je ka maa saseyori leka eto aabo – Soji Ganzallo
Ọga agba fajọ eleto abo nipinlẹ Ogun iyẹn Ogun State Community, Social Orientation and Safety Corps, ti ọpọ mọ si…
Read More » -
Gbogbo awa Gomina la fọwọ si idasilẹ ọlọpaa ibilẹ.awon Aṣòfin ko ni pe buwo luu
Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdu ti fi igbagbọ ẹ han pe awọn ọmọ ile igbimọ aṣofin to wa kaakiri…
Read More » -
Kontirola Afeni gbalejo kọmiṣanna Olopa Bode Ojajuni, won Panupo lati mu eto aabo pinpin lenu bode ipinle ogun.
Kontirola eṣọ aṣọbode nipinlẹ Ogun, Ọladapọ Afẹni ti ṣeleri fun Oga olopa pe ajọṣepọ to danmọran maa wa laarin awọn…
Read More » -
Opiration Kosaye: Gomina Abiodun dupe lowo awon oga olopa IGP Disu, Ogun, àti Eko fún ti eka olopa ti won sese da sile lati ma koju awon ajinigbe.
Gomina Dapo Abiodun ni igbese ti oga olopa gbe yi ti ko jinijinni ba awon ajinigbe o si ti je…
Read More » -
Ijoba mi ko ni Faye gbà awon ajinigbe nipinle Ogun-Gomina Dapo Abiodun
Gomina Ipinle Ogun, Omoba Dapo Abiodun, ti Fi da awon olugbe ipinle ogun loju pe ijoba oun ko ni Faye…
Read More » -
Ajo eso Alaabo Amotekun ti n gba osise bayi.
Ajo aso Alaabo ti a mo si Amotekun, ni ijoba ipinle Ogun ti fun lase pe ki won gba awon…
Read More »