Month: July 2026
-
ÒṢÈLÚ
Ko si nnkan to n je PDP mo ni Guusu Yewa- Alaaji Kayode Sunmola Adewale
Olóye Kayode Sunmola Adewale to ti figba kan je Alaga ibile Guusu Yewa to si je okon gboogi ninu ẹgbẹ…
Read More » -
Komisana olopa Bode Ojajuni sabewo si idiroko,ilaro o si ro won lati tunbo maa gbà àlaafia laaye.
CP BODE OJAJUNI to je komisana olopa ipinle ogun ti gbe abewo re de idiroko ati ilu ilaro tiise olu…
Read More » -
ÈTÒ ÀÀBÒ
Ajosepo to danmoran to wa laarin awa eleto aabo nipinle ogun lo je ka maa saseyori leka eto aabo – Soji Ganzallo
Ọga agba fajọ eleto abo nipinlẹ Ogun iyẹn Ogun State Community, Social Orientation and Safety Corps, ti ọpọ mọ si…
Read More » -
LÁGBÓ-ÌDÁRAYÁ
Ìdíje bọ́ọ̀lù AFENI CUP 2026 ni a gbe kale láti fi se ilaniloye fawon akeko nipa ewu to wa ninu ise fayawo-Kontirola Afeni
Ajo eso Asobode eka akoko nipinle ogun ti sagbateru eto idije boolu afesegba kan ti won pe ni Afeni Cup…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Die lara awon eto idagbasoke to kan Ile Yewa-Awori laarin odun meta isakoso Aare Bola Tinubu
Bi le se n mo tile n su ni ojo naa ti Aare Tinubu de ipo Aare orile ede Naijiria…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Omooba Segun Adewale darapo mo Alajobi to n sagbateru fun Seneto Solomon Olamilekan YaYi lori ibo odun 2027
Omooba Segun Adewale ti Opo mo si OSA ti darapo mo ẹgbẹ kan tawon Omo Iwo-oorun ipinle ogun kojo lati…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
OGUN 2027, YAYI dupe lowo Gomina Abiodun fun atileyin re lori Ile Ipolongo ibo ti oun ko silu Abeokuta.
Ese o gbero nilu Abeokuta nigba ti Aṣòfin agba Seneto Solomon Olamilekan Adeola ti Opo mo si YaYi si Ile…
Read More » -
ÌWÀ Ọ̀DARÀN
Owo awon So-safe ba afurasi to ji eeyan gbe to tun n fipa baalopo
Ẹgbẹ́ ajo eso alaabo So-Safe Corps, ipinle ogun ti mu afurasi kan tí wọ́n fi ẹ̀sùn ìjínigbé àti ìfipábánilòpọ̀ kan…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Ko sọrọ baba isalẹ ninu ẹgbẹ wa, ọjọ iwaju araalu lo jẹ wa logun -Akerele alaga ẹgbẹ oṣelu BOOT nipinlẹ Ogun.
Abiọdun Akerele, alaga fẹgbẹ oṣelu BOOT, iyẹn Because of our tomorrow ti sọ pe idasilẹ ẹgbẹ ọhun ko nii ṣe…
Read More »
