ÌRÒYÌN
-
Ìyáwo Ààrẹ Tinubu,se ifilole ibudo ounje fawon mekunnu, o tun fun Ọmọ odun mejila to n yaworan ni ₦10 Milionu
Seneto Oluremi Tinubu to je Iyawo Aare orileede Naijiria ti fun Omo odun mejila to ya Aworan iyawo Aare sinu…
Read More » -
Bi Gomina Dapo Abiodun se gbe eto isejoba re le Opo marun-un ti a mo si ISEYA, lo je ko maa saseyori- Akinmade
Oludamọran fun Ọmọọba Dapọ Abiọdun tii ṣe Gomina Ipinlẹ Ogun lori Eto Iroyin ati Ọgbọn Atinuda, Ọgbẹni Kayọde Akinmade lo…
Read More » -
Oloye Olabode George di baba egbe ‘League of Yoruba Media Practitioners’
Ẹgbẹ́ awon oniroyin ede Yoruba, iyen ‘League of Yoruba Media Practitioners’ (LYMP) ti fi oye baba egbe naa da agba…
Read More » -
Ẹgbẹ Legacy brothers IJOUN ṣe ìpàdé won dori ipinu bi ilosiwaju se fe ba ilu ijoun ati Ile Yewa lapapo.
Ẹgbẹ Legacy Brothers ijoun je okon gboogi ninu awon ẹgbẹ to wa Nile ketu, to si n sise Lori bi…
Read More » -
Kontirola Muhammed Shuaibu fa apo igbó le ajọ to n gbogun ti oogun oloro lọwọ
Kontirola ajo eso asobode nipinle ogun, kontirola Muhammed Shuaibu ti fa apo to kun fun igbo, eyi to jẹ ẹgbẹrun…
Read More » -
Alase ati Oludari egbe aanu SOj se ayeye ajodun odun marundinlogota Ibd lona ara
Alase ati oludari egbe aanu kan tawon eeyan mo si SOJ charity foundations.Ase oluwani lo seto adua to si tun…
Read More » -
Kontirola Muhammed Shuaibu ro awon ofisa ti won gba igbega lati maa sise kara ki won si je olooto lenu ise won
Oni ojo kejidinlogbon osu kini odun egbaa odun o-le marunlelogun yi ti Kontirola Shuaibu Muhammed n dekoreeti awon aadota ole…
Read More » -
Maa ko Ile ijosin musulumi mii to ni Iwe ase ijoba sinu ogba Ile Eko awa asobode to wa ni idiroko-kontirola James Ojo
Kontirola James Ojo ti Fi da awon eeyan loju pe Oun Maa ko Ile ijosin awon musulumi mii to ni…
Read More »