ÌṢÒWÒ
-
Kontirola Otunla seleri ajosepo to dan moran pelu awon olokoowo to wa lenu bode Idiroko.
Ọga agba aṣọbode ipin akoko nipinlẹ Ogun, kontirola G A Ọtunla ti mu un da awọn to n sowo lenu…
Read More » -
Ajo eso asobode ipinle Ogun gba lresi,taya moto, ati igbo pelu ibon lowo awon onifayawo.
Kontirola Muhammed Shuaibu to n dari ajo eso asobode akoko nipinle ogun ti fi awon eru ti won gba laarin…
Read More » -
Eso asobode fa Milionu meje owo sefa to je Milionu metadinlogun owo naira le ajo EFCC lowo nipinle Ogun
Oga agba ajo eso asobode nipinle ogun Kontirola Muhammed Shuaibu ti fa Milionu meje owo sefa to je milionu metadinlogun…
Read More » -
Eso asobode ipinle ogun pa #275,835,406 wole sapo ijoba apapo lodun 2024 ….. won gba Igbo,Iresi,Ada ati eru fayawo mii losu kini odun 2025.
Oga agba eso asobode nipinle Ogun, Kontirola Shuaibu Muhammed ti je ko di mimo pe milionu lona igba ole ni…
Read More » -
Ayajo ojo awon Asobode, Kontirola Shuaibu Seleri lati mu sikani masinni to n sayewo eru to wa ni idiroko soji pada .
Kontirola Muhammed Shuaibu to n dari iko asobode to wa ni eka akoko nipinle Ogun, iyen Ogun 1komand ti seleri…
Read More » -
Kontirola Muhammed Shuaibu gba Moto,lresi ati awon eru fayawo to po laarin ose kan….o si kilo fawon onifayawo lati fi ipinle ogun sile.
Kontirola Muhammed Shuaibu to Bere ise gege bi oga agba ajo eso asobode nipinle Ogun ni nnkan bi ose kan…
Read More » -
Maa riipe opin de ba ise fayawo ni ipinle ogun-Kontirola Muhammed Shuaibu
Kontirola Muhammed Shuaibu ti je ko di mimo pe oun ma mu opin de ba ise fayawo nipinle Ogun. Shuaibu…
Read More » -
Kontirola James ojo ti fa oogun oloro ti won gba lowo awon onifayawo le ajo NDLEA lowo
Kontirola James Ojo to n dari eka akoko ajo eso asobode nipinle Ogun ti fa oogun oloro to le ni…
Read More »