ÈTÒ Ẹ̀KỌ́
-
Nnkan de awon Adari Ile eko Ijoba ati Aladani ti n be ijoba ipinle Ogun, won ni ki won ma fagile ayeye ikekogboye awon akeko.
Ni kete ti ijoba ipinle Ogun ti Fi Iroyin sita pe ki Ile eko Ijoba ati Aladani fagile ayeye ikekogboye…
Read More » -
Bi ile eko FPI se di FUTI dara gan-an…o si maa sanfaani pupo fawon akeko ati araalu- Dokita Mukail Akinde
Dokita Mukail Akinde to je rekito ile eko gbogbonise ilaro titi won fi yi oruko naa pada si FUTI iyen…
Read More » -
Akinde ro omo naijiria lati wo awon aseyori ti adari ajo JAMBU se tele.. . ki won to sedajo lori isele to waye ninu idanwo Jambu odun 2025
Rekito ile eko gbogbonise ilaro, omowe Akinde Mukail Aremu ti ro awon omo orile ede Naijiria pe ki won…
Read More » -
Ile eko gbogbonise ilaro gba akeko egberun mokanla ati oodunrun-le-merin-din-logun wole si ipele ND,HND ati ND Odfel pelu HND odfel ti saa ikeko 2024/2025
Oni ojo kerinla osu keta odun egbaa odun ole marunlelogun yi ni ile eko gbogbonise to wa nilu ilaro pari…
Read More » -
E yera fun iwa odaran, e lo imo ti e gba ni FPI lati mu ilosiwaju ba orile ede Naijiria – Dokita Mukhail Akinde.
Rekito ile eko gbogbonise ilaro, Dokita Mukhail Akinde ti ro awon akeko egberunmeje lgba odin mewa ti won sese jade…
Read More » -
Nnkan ma a yipada leka eto oro aje tijoba ba pase fawon eeyan lati maa ra nnkan taa se lorileede Naijiria-Mukhail Akinde
Rekito ile Eko Gbogbonise ilaro, Dokita Mukhail Akinde je ko di mimo pe Nnkan ma a yipada leka eto oro aje…
Read More » -
Foto nibi ayeye ojo akoko ajodun aadota odun Ile Eko Emmanuel
Oba Kehinde Gbadewole Olugbenle Eyi ni foto bi awon akeko naa se n de si iwaju ile epo Himra niwaju…
Read More »
