ÌRÒYÌN YÀJÓYÀÓ
Trending

Sẹnetọ Ọlamilekan Adeọla ni lpò Gomina lpinle Ogùn kàn lọ́dún 2027-Ọnọ.Latifat Ajayi

Ọnanrebu latifat Ajayi to n soju Guusu Yewa níle ìgbìmọ̀ asòfin ìpìnlẹ̀ ògun, tó tún jẹ lgbakejì abenugan nìle  lgbimo asofin ti fidi rẹ mulẹ̀ pé Sẹnetọ Olamilekan Adeọla Yayí lo maa di gomina ipinle ogun lọun 2027.

Ọnọrebu Latifat sọrọyi nígba ti wọn n ṣí lyara lkawe ti Sẹnetọ Adeọla kọ sile ekọYewa College to wa nilu llaro ni guusu Yewa ni lpinle ogun lojo kokonlelogun osu kewa odun 2024.

Ajayi ni, awon ise idagbasoke ti Adeola n se jakejado ile Yewa to si ma kari gbogbo lpinle ogun laipe lo ma je ko yato laarin awon oludje to ku nipine ogun, ti awon eeyan si maa dibo fun.

” Sẹnetọ Adeọla ko bere owo lọwọ ẹnikẹni ko si wá lati ko owo jẹ, amọ o wa lati mu idagbasoke tí ko tii si iru rẹ ri ba lpinle ogun”.

Onọrebu Latifat wa ro awọn eeyan lati fi ibo wọn gbe Sẹnetọ Adeọla wole sipo gomina ti asiko ba to.

Bẹ lo rọ awọn ọmọ Yewa-Awori lati fimo se okan ti asiko ba to.

Eyi ni awon nnakan ti won si naa ati ibi ti won ti sii.

Akoko ile iwosan ni okeodan Primary Health Centre, Okeodan, opopona  Moboluwaduro/Ago Ilobi Road ati sisi Olokuta Road, Owode pelu opopona Bible College Alagbon , Owode awon mii ni lyara ikeko mejia ni Area Community High School, Owode.

Won tun Si  iyara  ikawe mejila ni CAC Primary School, Abekoko, Ilaro,  Igbo Aje Ultramodern Market, Ilaro ati oja Sayedero Ultramodern Market, Ilaro

Iyara ikawe mejia ni Yewa (Egbado) College, Ilaro, ICT Center at School of Nursing, Ilaro, ICU at General Hospital, Ilaro lle lwosan ni Pahayi, Ilaro ati Ogba olopa ni Pahayi Police Station, Ilaro,Sisi Ad titi etutu GRA Road, Ilaro ati sisi opopona Union Bank/Ona Egbo Road, Ilaro

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button