Month: May 2026
-
ÌDÁJỌ́
Ni bayi ti Ile ejo ti sun eto igbejo siwaju awa agbejoro ti panupo lati mu eepo kuro laarin Alikama wa – Ogbeni Samson
Ogbeni Samson to je Alaga awon agbejoro eka ti ilaro ni ipinle Ogun lo soro yi fawon oniroyin ninu ogba…
Read More » -
ÌWÀ Ọ̀DARÀN
Eso Asobode gba ọkọ̀ Boosi to ko aṣọ ologun, ati igbo ni opopona Sagam-Benin
Ilé iṣẹ́ aṣọ́bodè Nàìjíríà (NCS), eka akoko ni ipinle Ogun to wa ni Idiroko, ti gbé ọkọ̀ akérò olówó iyebíye…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Ọnarebu Oluṣọla Arikẹ Ayekootọ jawe olubori gẹgẹ bi oludije ADC fun ipo aṣoju-ṣofin agbegbe Alimọṣọ,ipinlẹ Eko
Se ni idunnu n ṣubu layọ fun gbajumọ sọrọsọrọ, to tun jẹ agba oniroyin nni, Ọnarebu Oluṣọla Arikẹ, tọpọ awọn…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Sẹ́nétọ̀ Adeola rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti dìbò fun Aare Tinubu leekeji,ko le pari awon ise ribiribi to n se lowo
Olùdíje sipo gómìnà labe Asia ẹgbẹ Oselu ti (All Progressives Congress) ni Ipinle Ogun, Sẹ́nétọ̀ Solomon Olamilekan Adeola, ti opo…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Seneto Adeola dupe lowo awon oludibo, o seleri eto ijoba to deledoko, o wa ro won ki won jade lati dibo Aare lojo Abameta
Seneto Solomon Olamilekan pelu Iyawo re ati oludije sipo Gomina labe Asia ẹgbẹ Oselu ADC ninu eto idibo odun 2023…
Read More »