ÌRÒYÌN YÀJÓYÀÓ
-
Ijoba ipinle ogun ti sun ojo to fe gbe eto isuna odun 2025 wa sile igbimo asofin di ojo mii
Iroyin ti ogbeni Sakiru Adebakin to je kilaaki ile igbimo asofin ipinle ogun fi sita loni ojokejidinlogbon osu kokonla odun…
Read More » -
A fi ki Gomina Dapo Abiodun gba wa lowo ipinle Eko, Se ni won wa n ti awon Soobu wa ni lpinle ogun nitori Owo ori – Ogbeni Zinsu Adebayo AKA Agbeloba.
Ogbeni ZINSU ADEBAYO aka AGBELOBA Lati Ere Zungotho to je olori awon oloja ni agbegbe Ere ni ijoba Ibile Ado…
Read More » -
Sẹnetọ Ọlamilekan Adeọla ni lpò Gomina lpinle Ogùn kàn lọ́dún 2027-Ọnọ.Latifat Ajayi
Ọnanrebu latifat Ajayi to n soju Guusu Yewa níle ìgbìmọ̀ asòfin ìpìnlẹ̀ ògun, tó tún jẹ lgbakejì abenugan nìle lgbimo…
Read More » -
Abiodun Akinlade Fi Keke,Okada,Taya Okada ati firigi pelu ero Ata ati Genereto seto ironilagbara fawon Olugbe Guusu Yewa/Ipokia
Onorebu Abiodun Akinlade to n soju Guusu Yewa/Ipokia nile igbimo asofin Kekere nilu Abuja ti seto ironilagbara fawon Olugbe Guusu…
Read More » -
Awon Omo Niajiria si n duro de esi lwadi ti Ile Ise olopa ipinle Ogun se lori iku akeko to waye nilu ilaro
Iroyin iku Falolu Ope Oluwaseun ti Omo odun meedogun lo gba Igboro lojo kerindinlogun osu kesan odun 2024. Awon to…
Read More » -
Gomina Dapo Abiodun ti pase pe ki won ma San egberunlonametadinlogorin gege bi Owo osu osise to kere ju lo nipinle Ogun.
Se ni Inu awon osise ijoba ipinle Ogun n dun sinkin nigba ti Gomina Dapo Abiodun buwolu egberun lona metadinlogorin…
Read More »