Lobaloba
-
Ori ile Yewa ni Olorunda wa kiise ile Egba, ki awon Egba ma yan oba le wa lori- Awon olugbe Olorunda
Awon omo ilu ati olugbe Abule Olorunda ni ijoba ibile Ariwa Abeokuta ni ipinle Ogun ti ke gbajare sita…
Read More » -
Ayẹyẹ ọdun kọkalelogun ti Olu Itori gori itẹ ti bẹrẹ
Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii ni wọn bẹrẹ ayẹyẹ ọdun kọkanlelogun ti Olu-Itori, Ọba Fatai Akorede Akamọ, gori itẹ gẹgẹ…
Read More » -
Nitori ipo ọba: Awọn kan n lepa ẹmi mi o- Ọmọọba Adekọya Adefowora
Ọmọọba Adekọya Babajide Adefowora, ti bẹ gbogbo awọn ọmọ Naijiria pe ki wọn fi adura ran oun lọwọ, nitori…
Read More » -
Baale Keesan orile oloye AbdulWaheed Abodunrin Abiodun ro ijoba ipinle Ogun lati wa se opopona ati afara to wo ilu keesan orile
Ojo kerin osu kinni odun egbaa odun ole marunlelogun ni Baale, Igbimo ilu ati Omo ilu Keesan Orile se ayajo…
Read More » -
Ayeye oniberin ti Baale Keesan orile oloye Abodunrin Adeyemi seto re ti fe bere
Baale Keesan orile ni Ariwa Abeokuta, Oloye Waheed Abiodun Abodunrin Adeyemi ti salaye pe gbogbo eto lo ti pari fun…
Read More » -
Ko sija laarin emi ati Gomina Dapo Abiodun, awon eeyan ti won Fe di Gomina bii temi ni won fe da aarin wa ru- Sen.Adeola Yayi
Seneto Olamilekan Adéola Yayi ti je ko da awon eeyan loju pe ko sija laarin Oun ati Gomina lpinle Ogun,…
Read More »
