Month: January 2025
-
ÌṢÒWÒ
Eso asobode ipinle ogun pa #275,835,406 wole sapo ijoba apapo lodun 2024 ….. won gba Igbo,Iresi,Ada ati eru fayawo mii losu kini odun 2025.
Oga agba eso asobode nipinle Ogun, Kontirola Shuaibu Muhammed ti je ko di mimo pe milionu lona igba ole ni…
Read More » -
ÌṢÒWÒ
Ayajo ojo awon Asobode, Kontirola Shuaibu Seleri lati mu sikani masinni to n sayewo eru to wa ni idiroko soji pada .
Kontirola Muhammed Shuaibu to n dari iko asobode to wa ni eka akoko nipinle Ogun, iyen Ogun 1komand ti seleri…
Read More » -
Seneto olamilekan mu ife pada si Yewa-Awori nitori ibo 2027
Awon nnkan to sele nibi ayeye ajodun oronna to sese pari nilu ilaro ti i se olu ile Yewa Aworì…
Read More » -
ÌSÌN
Sunday ljidele sin Oku mama re Elisabeti Gbemisola ijidele tilu tifon.
Onimoero Sunday ljidele to fi ilu Eko se ibugbe lo ti se ayeye ikeyin fun mama re oloogbe Elisabeti Gbemisola…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Ko si gomina to se daadaa to gomina Dapo Abiodun- Komuredi .Isa olude
Komuredi Isa olude to je alaga awon osise feyinti nipinle Ogun ti sapejuwe gomina lpinle ogun omooba Dapo Abiodun gege…
Read More » -
Lobaloba
Baale Keesan orile oloye AbdulWaheed Abodunrin Abiodun ro ijoba ipinle Ogun lati wa se opopona ati afara to wo ilu keesan orile
Ojo kerin osu kinni odun egbaa odun ole marunlelogun ni Baale, Igbimo ilu ati Omo ilu Keesan Orile se ayajo…
Read More »
