Month: March 2025
-
ÌṢÒWÒ
Eso asobode fa Milionu meje owo sefa to je Milionu metadinlogun owo naira le ajo EFCC lowo nipinle Ogun
Oga agba ajo eso asobode nipinle ogun Kontirola Muhammed Shuaibu ti fa Milionu meje owo sefa to je milionu metadinlogun…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Pẹlu owo tabua to n wọle sapo Eko, Iya ṣi tun n jẹ awọn araalu – Gbadebo Rhodes Vivouṣ
Adijedupo gomina nipinlẹ Eko labẹ asia ẹgbẹ oselu labour party ni ọdun 2023 Gbadebo Rhodes-Vivour ti bu ẹnu atẹ lu…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Ko si egbe to le se bi i egbe oselu PDP lorileede yi-Bọde George
Baba wa, njẹ e le sọ fun wa ibi ti ẹgbẹ oṣelu PDP wa lakooko yii? Gbogbo eeyan naa…
Read More » -
ÈTÒ Ẹ̀KỌ́
Ile eko gbogbonise ilaro gba akeko egberun mokanla ati oodunrun-le-merin-din-logun wole si ipele ND,HND ati ND Odfel pelu HND odfel ti saa ikeko 2024/2025
Oni ojo kerinla osu keta odun egbaa odun ole marunlelogun yi ni ile eko gbogbonise to wa nilu ilaro pari…
Read More » -
Lobaloba
Ori ile Yewa ni Olorunda wa kiise ile Egba, ki awon Egba ma yan oba le wa lori- Awon olugbe Olorunda
Awon omo ilu ati olugbe Abule Olorunda ni ijoba ibile Ariwa Abeokuta ni ipinle Ogun ti ke gbajare sita…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Orileede Naijiria maa ni illosiwaju ti a ba se ara wa ni osusu owo, ti a si yera fun iwa eleyameya-Rhodes-Vivour
Gbajugbaja ni Ayaworan-ile Gbadebọ Rhodes-Vivour jẹ lagboole oṣelu lorileede Naijiria, paapaa nipinlẹ Eko. Ọkan pataki lara awọn to di ẹgbẹ…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Omooba Rasheed Adewusi Seto ironilagbara fawon akosemose atawon Agbe to din die loodurun 300 ni ipinle Ogun.
Oni ojo kini osu keta odun egbaa odun o-l-e marundinlogun yi ni omooba Rasheed Adewusi ti opo awon eeyan mo…
Read More »

