Alase ati Oludari egbe aanu SOj se ayeye ajodun odun marundinlogota Ibd lona ara

Alase ati oludari egbe aanu kan tawon eeyan mo si SOJ charity foundations.Ase oluwani lo seto adua to si tun fun awon eeyan lebun lati sayeye ajodun ogota odun o din marun ti alase ati oludari ile itura lbd (Ayelade 1) se lojo keta osu keta odun egbaa odun o le marunlelogun yi.
Oloye Obasanjo Ojugbele omo Ayelade 1 to je akeweje ilu Ebute-Igbooro, to si tun je alase ati oludari Soj charity foundations Ase oluwani lo seto adura to si tun fun awon to ku die kaato fun lebun loruko Alaaji Ibrahim Dende Egungbohun ( Ayelade 1) lati fi sami ayeye ajodun ojo ibi naa.
Nibi ti SOJ ti n pin ebun naa fawon to ku die kaato fun nilu Abeokuta tiise olu ilu ipinle ogun ni akoroyin kan to mo Soj ti rii nigba to n fun awon to ku die kaato lebun loruko ibd ti won si fe bere si ni se fidio re amo to n so fun won pe oun o fe ki won fidio oun, tori lbd Ayelade 1 ti oun wa pin nnkan loruko e ko fe nnkan sekarimi.
Leyin to pin ebun naa tan lo so be fun akoroyin to ri naa;
O ni, ” Mi o fe ke se fidio mi leekan tori eni ti mo wa se nnkan loruko e ma n soore amo kii se oore sekari mi ,Ka sooto iru alaaji sowon gan an .

Idi niyen ti mo se pinu lati ma se atileyin fun won nigba gbogbo.
Adura mi nipe ki olorun ma bami fi iso re sowon ni gbogbo ibi ti won ba n lo.
Ogbeni Abdulahi
to wa lara awon ti won gba Ebun naa dupe pupo lowo Soj o si se adura fun olojo ibi ati awon molebi re.




