Year: 2025
-
ÈTÒ Ẹ̀KỌ́
Ile eko gbogbonise ilaro gba akeko egberun mokanla ati oodunrun-le-merin-din-logun wole si ipele ND,HND ati ND Odfel pelu HND odfel ti saa ikeko 2024/2025
Oni ojo kerinla osu keta odun egbaa odun ole marunlelogun yi ni ile eko gbogbonise to wa nilu ilaro pari…
Read More » -
Lobaloba
Ori ile Yewa ni Olorunda wa kiise ile Egba, ki awon Egba ma yan oba le wa lori- Awon olugbe Olorunda
Awon omo ilu ati olugbe Abule Olorunda ni ijoba ibile Ariwa Abeokuta ni ipinle Ogun ti ke gbajare sita…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Orileede Naijiria maa ni illosiwaju ti a ba se ara wa ni osusu owo, ti a si yera fun iwa eleyameya-Rhodes-Vivour
Gbajugbaja ni Ayaworan-ile Gbadebọ Rhodes-Vivour jẹ lagboole oṣelu lorileede Naijiria, paapaa nipinlẹ Eko. Ọkan pataki lara awọn to di ẹgbẹ…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Omooba Rasheed Adewusi Seto ironilagbara fawon akosemose atawon Agbe to din die loodurun 300 ni ipinle Ogun.
Oni ojo kini osu keta odun egbaa odun o-l-e marundinlogun yi ni omooba Rasheed Adewusi ti opo awon eeyan mo…
Read More » -
Lobaloba
Ayẹyẹ ọdun kọkalelogun ti Olu Itori gori itẹ ti bẹrẹ
Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii ni wọn bẹrẹ ayẹyẹ ọdun kọkanlelogun ti Olu-Itori, Ọba Fatai Akorede Akamọ, gori itẹ gẹgẹ…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
E wo ohun to ye ki opo oloselu se lagbegbe won lorileede Naijiria
Ni bayi ti Babangida ti fi apeere rere lele fawon asiwaju ati oloselu Naijiria, o ye ki awon agbaagba oloselu…
Read More » -
ÈTÒ Ẹ̀KỌ́
E yera fun iwa odaran, e lo imo ti e gba ni FPI lati mu ilosiwaju ba orile ede Naijiria – Dokita Mukhail Akinde.
Rekito ile eko gbogbonise ilaro, Dokita Mukhail Akinde ti ro awon akeko egberunmeje lgba odin mewa ti won sese jade…
Read More » -
LÁGBÓ-ÌDÁRAYÁ
YEWA Unity Cup (Youth Championship) 2025
Eyi ni awon ifesewonse to fe waye loni ojo kerindinlogun osu keji odun egbaa odun o-le marunlelogun A Alaari…
Read More » -
LÁGBÓ-ÌDÁRAYÁ
YEWA Unity Cup (Youth Championship) 2025
Eyi ni esi ifesewonse to waye laarin awon iko to wa ni ipin karun lojo keedogun osu keji odun egbaa…
Read More »
