LÁGBÓ-ÌDÁRAYÁ

YEWA Unity Cup (Youth Championship) 2025

Eyi ni esi ifesewonse to waye laarin awon iko to wa ni ipin karun lojo keedogun osu keji odun egbaa odun o-le marunlelogun yi

Awon ibi ti boolu naa ti waye ni  Idiroko, Ilaro, Ijoun, and Ijaka-Oke be ni awon lobaloba ti won wa ni awon agbegbe ti won ti gba boolu naa wa nibi idije naa.

Kabiyesi Olu ti Owode-Yewa, Alayeluwa Oba M.S Akindele, JP, Kabiyesi Onijale ti Ijale-Ketu, Alayeluwa Oba B. B Oyero, pelu awon oloye lati Igan Alade, Iwoye, Idiroko, Ifoyintedo, Ayetoro ati Imasayi; ati asoju egbe  YPDC, ati awon oloye egbe  Yewa Youth Association wa nibe pelu , be ni awon agbofinro ati awon eeyan jankanjankan mii wa nibe pelu

 

A
Imasayi FC = 0
vs
Ayetoro Uni. FC = 3

B


Ifonyintedo FC = 1
vs
Idiroko FC = 0

C

Igan-Alade FC = 1
vs
Ijale-Ketu FC = 0

D


Owode-Yewa FC =1
Vs
Iwoye-Yewa FC = 0

 

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button