Month: July 2026
-
ÌṢÒWÒ
Gomina Dapo Abiodun ti fowosi ise agbe wara $250m pe ko bere ni Iwo-Ọorun ipinle ogun.
Gomina ipinle ogun omooba Dapo Abiodun ti fowosii pe ki Ile ise kan ti a mo si Pure Dairy Herds…
Read More » -
ÌWÀ Ọ̀DARÀN
Eyi ni Iroyin awon aseyori ti Ile ise olopa ipinle ogun se lawon agbegebe bii llaro,Ibafo,Mowe, Adatan, àti Ode-Remo.
Ninu Iroyin ti alukoro olopa ipinle ogun Amofin Oluseyi Babaseyi fi ranse si Ile ise iwe Iroyin Yewa lo ti…
Read More » -
ÌWÀ Ọ̀DARÀN
Owo eso alaabo so-safe ba awon ti won fe ji eeyan gbe ni IJU-OTA
Eso alaabo So-Safe Corps, ti ṣe àṣeyọrí láti dènà ìjínigbé àti ìjalè tí awọ́n kan gbèrò láti ṣe sí oníṣòwò…
Read More » -
ÌWÀ Ọ̀DARÀN
Ẹso alaabo So-Safe Corps, ti mú àwọn afurasi mẹ́ta tí wọ́n maa n ra epo Disu lowo osie Ile ise to n se ojú ọ̀nà Sokoto lagbegbe Ilaro.
Owo eso alaabo so-safe to wa ni Guusu Yewa ipinle ogun to ba awon afurasi ti won ma n lo…
Read More » -
ÈTÒ ÀÀBÒ
Opiration Kosaye: Gomina Abiodun dupe lowo awon oga olopa IGP Disu, Ogun, àti Eko fún ti eka olopa ti won sese da sile lati ma koju awon ajinigbe.
Gomina Dapo Abiodun ni igbese ti oga olopa gbe yi ti ko jinijinni ba awon ajinigbe o si ti je…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Iro ni won n pa,Gomina Dapo Abiodun ko ni ki enikeni maa kunle tabi dobale foun- Akinmade
Olubadamoran Gomina Dapo Abiodun lori oro Iroyin Ogbeni Kayode Akinmade ti fesi si Iroyin eleje kan ti Ile ise Iroyin…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Ìdílé Obasanjo pín si meji nítori oselu awon meji tele Yayi nigba ti Iyabo ati awon toku tele Ladi Adebutu
Nnkan ti koseleri ni ipinle ogun lo n sele lasiko ti Seneto Solomon Olamilekan Adeola YaYi setan lati du ipo…
Read More » -
ÌṢÒWÒ
Eso Asobode idiroko gba eru fayawo to le ni ₦4.6bn láàrín ọjọ́ metalelogorin, wọ́n sì pa #259.2m wole sapo ijoba apapo
Ilé Iṣẹ́ eso Asobode eka akoko nipinle ogun to wa ni idiroko ti gba awon eru fayawo to je Bilionu…
Read More »

