ÒṢÈLÚ

Ope ooo ! Seneto Olamilekan da isokan pada si Yewa- Awori

Isele to sele nibi ayeye ajodun orona to sese pari lojo kini osu kejila odun 2024 yi ti Fi han pe isokan ti n pada sile Yewa-Awori.

Ohun akoko ni bi Obalanlege to je Olori awon lobaloba nile Awori ati Olofin Adimula se wa nibi ayeye ajodun orona naa.

Omiran ni bi Seneto Opeyemi Bamidele Se fa owo  Seneto Olamilekan Adéola Yayi le Seneto Iyabo Anisulowo to ti figba kan ri lo soju Iwo-oorun ipinle Ogun nile igbimo asofin apapo nigba kan ri lowo.

Ohun to sele laarin Seneto Olamilekan Adéola Yayi ati Seneto Iyabo Anisulowo yi lo n je ki awon eeyan ma so pe idaniloju ti wa pe Seneto Olamilekan Adéola Yayi ti di Gomina ipinle Ogun ni odun 2027.

Bi awon lobaloba nile Awori se wa sibi  ayeye naa lo je ki awon kan ma a so pe wiwa ti won wa nibe  fihan pe awon ti won ma n daja sile laarin Iwo-oorun ipinle Ogun ko ni raye lati se be mo.

Be ni awon oloselu mii lati ilu Egba wa nibi ayeye naa

 

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button