ÀPILẸ̀KỌÒṢÈLÚ

E wo ohun to ye ki opo oloselu se lagbegbe won lorileede Naijiria

Ni bayi ti Babangida ti fi apeere rere lele fawon asiwaju ati oloselu Naijiria, o ye ki awon agbaagba oloselu bere si ni salaye awon nnkan to ti sele ninu oselu lagbegbe won fun omo Naijiria ni.

Ti opo ko ba le too sile gege bi ti Babangida se.se , won le pe ipade awon oniroyin ki won si so awon nnkan ti won mo nipa oselu lagbegbe won ati ipa ti won ko nibe .

Be lo se ye ko ri jakejado orileede Naijiria paapaa ipinle Ogun.

Amo Bawo lo se ma ri lara Eyin omo Yewa-Awori ti Agba oloselu kan ba jade sita to ni, Eni ti e fa kale nigbayen ti e ro pe ko wole sipo Gomina lo wole, amo awon baibai ni won ni kawon ma kede re gege bi Eni to jawe olubori lasiko naa ?.

looto iru re ko sele ri amo to ba wa sele nko?

Ki le ma se fun iru awon Eni bee, paapaa to ba je Baba tabi Mama yin ni.

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button