ÌRÒYÌN YÀJÓYÀÓ
Gomina Dapo Abiodun ti pase pe ki won ma San egberunlonametadinlogorin gege bi Owo osu osise to kere ju lo nipinle Ogun.

Se ni Inu awon osise ijoba ipinle Ogun n dun sinkin nigba ti Gomina Dapo Abiodun buwolu egberun lona metadinlogorin gege bi Owo osu osise to kere ju ni ipinle Ogun.
Leyin Ipade to waye pelu awon Oloriodo osise ni Iroyin naa jade



