ÀṢÀ ATI ÌṢE
-
Omi Odo OleOmi Odo Oleyo ma mu eto oro Aje ru gogo sii ti ijoba ba le satunse re bi Ori oke Olumo ati osun -osogbo- Ọba Amusa Dosunmu
Elebute ti ilu Ebute-Igbooro, Oba Amusa Adetunji Dosunmu, ti ke si ijoba ipinle ogun lati se wa tun Odo Oleyo…
Read More » -
A fi Gbadebọ jẹ oye Obalefun toripe o je ojulowo omo Yoruba – Ijọ Oloriṣa Parapọ
Ọrọ tun ti foju han pe ojulowo ọmọ bibi ilẹ Yoruna ni oludije gomina labẹ ẹgbẹ oṣelu Labour, nipinlẹ Eko,…
Read More » -
Ijoba fofinde kiko iresi ile okeere wole si Naijiria,tori kii se ile Adulawo ni won ti gbin in – Shuaibu Muhammed
Oga agba ajo eso asobode nipinle ogun, kontirola Mohammed Shuaib, ti so idi ti ijoba orileede Naijiria ko se gba…
Read More » -
Inu mi ko dun bi awon to sejoba siwaju mi ko se mu idagbasoke ba agbegbe yi….inu mi dun bi won se yi ayeye oronna si oni nitori mi-Gomina Dapo Abiodun
Gomina Dapo Abiodun ti fi aidunnu re han si bi awon to ti sejoba siwaju re nipinle Ogun ko se…
Read More » -
Nitori ki Gomina ipinle Ogun le wa sibi asekagba Oronna,won yi ayeye ajodun asekagba oronna si ojo isinmi.
Ninu iroyin kan ti oloye Lekan Asuni to je alaga ayeye ajodun oronna fi sita fawon oniroyin loni ojo kerindinlogbon…
Read More »