YEWA Unity Cup (Youth Championship) 2025
E si boolu ti o waye jakejado ile Yewa ni ojo kerinla osu keji odun egbaa odun o-le marunlelogun

Boolu gbigba naa waye ni Idiroko, Ado-Odo ,ati Ijoun .
Awon ti won je oba lawon agbegbe ti won ti gba boolu naa lo side eto naa.
Kabiyesi Onihunbo ti Ihunbo, Alayeluwa Oba J. O Adesiyan ran asoju wa ; Akeweje ilu Ilaro-Yewa, oloye Okebunmi; ati awon oloye laafin oba olugbenle naa wa soju fun kabiesi awon asoju egbe Yewa People Development Council (YPDC) naa wa nibe pelu .
Be ni awon lobaloba lawon agbegbe to ku naa ran awon asoju lo si gbogbo awon ibi ti eto boolu afesegba naa ti waye jakejado ile Yewa.
Eyi ni esi boolu to waye ni ojo kerin (Group Stage) Results
A
Agbara jawe olubori pelu ami ayo kan si odo
Agbara FC 1vs Itakun 0
B

Oniro-Agude FC jawe olubori pelu ami ayo marun si merin
Oniro-Agude FC = 5
vs
Ihunbo FC = 4
C
Oja odan FC jawe olubori pelu ami ayo kan si odo
Oja-Odan FC = 1
vs
Ebute-Igbooro = 0



