ÈTÒ Ẹ̀KỌ́ÌRÒYÌN ALÁWÒRAN
Foto Boolu ayeye aadota odun ile eko Emmanuel

Eyi ni awon aaworan to wa nibi ojo keta ahodun Emamanuel ti Ogun 2024.
akeko 1993 pelu awon oha ile eko ati oluko Emmanuel
awon akeko naa n fi ebun da awon akonimogba lola
AK n ba awon agbaboolu soro

Benson Solomon Bamidele to n dari awon ajo to n gbogun ti oogun oloro ya foto pelu awon akeko naa





