ÌRÒYÌN YÀJÓYÀÓ
Trending

A fi ki Gomina Dapo Abiodun gba wa lowo ipinle Eko, Se ni won wa n ti awon Soobu wa ni lpinle ogun nitori Owo ori – Ogbeni Zinsu Adebayo AKA Agbeloba.

Ogbeni ZINSU ADEBAYO aka AGBELOBA Lati Ere Zungotho to je olori awon oloja ni agbegbe Ere ni ijoba Ibile Ado odo Ota lo ke gbajare si ljoba Gomina Dapo Abiodun ti lpinle Ogun lati wa gbawon lowo awon ti won wa n gbowo Ori lowo awon oloja ninu awon soobu to wa lori ile lpinle ogun.

Ogbeni Zinsu Adebayo to je okon lara awon Adari agbegbe naa to so oro naa fun akowe iroyin Yewa  je ko di mimo pe se ni won ti awon Soobu awon ti ko fun won ni owo. Won si je ki won Mo pe won gbodo San Owo naa tori Abe ijoba Ibile Agbadarigi ni lipinle Eko ni awon Soobu naa wa.

Ogbeni ZINSU ADEBAYO ni Oun ati Ogbeni Potefa ati awon Odo agbegbe naa lawon jade siwon ti awon si je ki won Mo pe agbegbe naa ko si labe ljoba Ibile Agbadarigi. Bo ti Le je pe won tun ni ki Ogbeni Potefa  tele awon lo si llu Eko la

O ni, “o ye ki ijoba ipinle Ogun wa se aala naa daa daa kawon Olugbe lpinle Eko le mo aala laarin ipinle Eko ati ipinle Ogun ki won ma ba ma koja ibi to ye ki won ti ma gbowo ori”.

O tesiwaju pe nigba ti awon ti won n gba Owo Ori lawon soobu naa de lati ipinle Eko si llu Ere ni ljoba Ibile Ado odo Ota , lpinle ogun ti won bere si ni ja iwe naa fawon eeyan ti won si n ti Soobu awon eeyan jade siwon won si je ki won Mo pe Abe ijoba Ibile Ado Odo OTA ni ipinle Ogun ni  ni Ere wa kiise line Eko.

” A fe ki ijoba Gomina Dapo Abiodun wa da si oro na ki won si wa se ójú aala naa daadaa ki awon eeyan le mo Iyato laarin lpinle Eko ati Ogun”.

Be ni a fe ki won je ko di mimo fun ijoba ipinle Eko pe Ere kii se ipinle Eko ipinle ogun ni.

Lekan sii .A o Fe ki oro o se aala ko se aala laarin ipinle ogun ati ipinle Eko tun ma waye Mo a si Fe ki ijiba ipile ogun bawa da sii kiakia , ki ijoba ipile Eko to jewa maye

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button