ÈTÒ ÀÀBÒ
Ajo eso Alaabo Amotekun ti n gba osise bayi.

Ajo aso Alaabo ti a mo si Amotekun, ni ijoba ipinle Ogun ti fun lase pe ki won gba awon osise 700 sii, ki Eto aabo ba le tun bo ru gogo sii nipinle Ogun.
Ikede ti Oga agba ajo naa nipinle Ogun ajagunfeyinti Adedigba Fi Owo si lo Fi ye wa pe Eni keni to ba Fe lati darapo Mo osise Amotekun le lo foruko sile loju opo yi lori ero ayelujara tabi ko lo si ofisi awon Amotekun to ba wa ni Agbegbe re.
Abawole iluja naa Lori ayelujara ni ; ogunstateamotekun.com.ng.
Be ni o je ko di mimo pe Eto iforuko sile naa ma bere ni ojokokondinlogbon osu kewa ti o si ma pari ni ojo kejidinlogun osu kokonla.
Be ni Eto ayewo finni-finni fun awon ti won ba foruko sile lati ojo ma waye ni ojo karundinlogbon osu kokonla si ojo kokonla osu kejila odun 2024.