Lobaloba

Baale Keesan orile oloye AbdulWaheed Abodunrin Abiodun ro ijoba ipinle Ogun lati wa se opopona ati afara to wo ilu keesan orile

Ojo kerin osu kinni odun egbaa odun ole marunlelogun ni Baale, Igbimo ilu ati Omo ilu Keesan Orile se ayajo Keesan Orile.Baale Bere eto yi leyin  to se ayeye onibeta to se, ti awon eeyan jankanjankan si peju pese so be.

 Oloye AbdulWaheed Abodunrin Abiodun AAdeyemito je Baale Keesan orile dupe lowo gomina lpinle ogun  omooba Dapo Abiodun  fun bi o se n mu idagbasoke ba awon ig eriko ni ipinle Ogun,  o si wa ro gomina  ati ijoba ibile lati  mu awon ise idagbasoke naa de ilu keesan orile .

Die lara awon nnkan ti Baale n ro gomina lati wa se si keesan orile ni opopona to wole si ilu naa.Baale wa sapejuwe oju ona yi gegebi eleyi ti o je pakute idena idagbasoke ilu naa, nitori wipe opolopo ire oko awon agbe ni o maa nbaje soko won nigbati won ko ba le ko lo soja, bee sini awon onira paapaa nsa nilu naa nitori aiko dara ona yi.
Baale tesiwaju wipe Igbimo ilu naa ti bere ise riri opo ina monamona ki awon olokowo le wa da okowo won sibe, idi siniyi ti awon fi rawo ebe si Ijoba lati boju aanu wolu naa fun atunse si oju ona won .
Baale Adeyemi soo di mimo wipe laarin odun kan abo ti awon gba isakoso olori ilu naa atunse ti ba ile iwosan , ile eko, ipese omi ero pelu ohun amayederun nilu.

Be ni Baale ro awon omo ilu naa lati wa dasesile ninu ilu naa ki idagbasoke le ba ilu keesan orile.

 

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button