Year: 2026
-
ÒṢÈLÚ
OGUN 2027, YAYI dupe lowo Gomina Abiodun fun atileyin re lori Ile Ipolongo ibo ti oun ko silu Abeokuta.
Ese o gbero nilu Abeokuta nigba ti Aṣòfin agba Seneto Solomon Olamilekan Adeola ti Opo mo si YaYi si Ile…
Read More » -
ÌWÀ Ọ̀DARÀN
Owo awon So-safe ba afurasi to ji eeyan gbe to tun n fipa baalopo
Ẹgbẹ́ ajo eso alaabo So-Safe Corps, ipinle ogun ti mu afurasi kan tí wọ́n fi ẹ̀sùn ìjínigbé àti ìfipábánilòpọ̀ kan…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Ko sọrọ baba isalẹ ninu ẹgbẹ wa, ọjọ iwaju araalu lo jẹ wa logun -Akerele alaga ẹgbẹ oṣelu BOOT nipinlẹ Ogun.
Abiọdun Akerele, alaga fẹgbẹ oṣelu BOOT, iyẹn Because of our tomorrow ti sọ pe idasilẹ ẹgbẹ ọhun ko nii ṣe…
Read More » -
Omooba Segun Adewala gbosuba fawon Oba Iwo-oorun ipinle ogun bi won se da Owo Ladi Adebutu pada
Omooba Segun Adewala ti a tun mo si OSA to da ẹgbẹ (OSA For YaYi) sile lati ma Fi polongo…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Gomina Dapo Abiodun to fa Seneto Adeola le awon lobaloba ijebu lowo
Gomina Ipinle Ogun, Omooba Dapo Abiodun, ti fi oludije gomina (All Progressives Congress) Seneto Solomon Olamilekan Adeola, ati igbakeji re…
Read More » -
ÈTÒ ÀÀBÒ
Gbogbo awa Gomina la fọwọ si idasilẹ ọlọpaa ibilẹ.awon Aṣòfin ko ni pe buwo luu
Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdu ti fi igbagbọ ẹ han pe awọn ọmọ ile igbimọ aṣofin to wa kaakiri…
Read More » -
ÈTÒ ÀÀBÒ
Kontirola Afeni gbalejo kọmiṣanna Olopa Bode Ojajuni, won Panupo lati mu eto aabo pinpin lenu bode ipinle ogun.
Kontirola eṣọ aṣọbode nipinlẹ Ogun, Ọladapọ Afẹni ti ṣeleri fun Oga olopa pe ajọṣepọ to danmọran maa wa laarin awọn…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Bí Tinubu ba fún àwọn ọmọ Yoruba ti ko ba dibo fun nípò ní sáà kejì, mo ma bínú si gidigidi-Ṣẹgun Ṣowunmi
Ojulowo Omo ẹgbẹ Oselu PDP ni mi sugbon mo faramo eto idagbasoke Aare Bola Tinubu, eleyi ti kọjá oro ẹgbẹ…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Omooba Segun Adewale, to dije fún ipò gómìnà tẹ́lẹ̀, ti n Satileyin fun Seneto Adeola Yayi to n dije fun ipo Gomina ninu ẹgbẹ Oselu APC lọdún 2027.
Omooba Segun Adewala ti Opo mo si (OSA) to dije fún ipò Gómìnà ní Ìpínlẹ̀ Ogun tẹ́lẹ̀,, ti bere si…
Read More »
