ÒṢÈLÚ
-
Aare awon Odo igun mereerin ipinle ogun Riye G4 se ipade,won fenuko lori awon nnkan ti awon Odo maa se fu eto idibo 2027
Ni bayi awon ti won je Aare ẹgbẹ́ awon ọ̀dọ́ lawon agbègbè mẹ́reerin ti won pin awon Odo si ni…
Read More » -
Ojoojumọ lawọn araalu darapọ mọ ẹgbẹ oṣẹlu NDC ipinlẹ Ogun- Fẹmi Alao
Alaga fẹgbẹ oṣelu NDC nipinlẹ Ogun Fẹmi Alao, ti sọ pe ọrọ ẹgan ẹgbẹ wọn ti n gbilẹ daadaa nipinlẹ…
Read More » -
Rotimi Geroge- Taylor, oludije fun ipo sẹnetọ ni Ogun Central sọ pe, “Bi ogo ti n jẹ ti Ọlọrun, mo maa wọle ibo lọdun 2027.
Ọnarebu Rotimi George Taylor, oludije fun ipo sẹnetọ ni agbegbe Ogun Central, pe bi ogo ti n jẹ ti Ọlọrun,…
Read More » -
Iro ni won n pa,Gomina Dapo Abiodun ko ni ki enikeni maa kunle tabi dobale foun- Akinmade
Olubadamoran Gomina Dapo Abiodun lori oro Iroyin Ogbeni Kayode Akinmade ti fesi si Iroyin eleje kan ti Ile ise Iroyin…
Read More » -
Ìdílé Obasanjo pín si meji nítori oselu awon meji tele Yayi nigba ti Iyabo ati awon toku tele Ladi Adebutu
Nnkan ti koseleri ni ipinle ogun lo n sele lasiko ti Seneto Solomon Olamilekan Adeola YaYi setan lati du ipo…
Read More » -
Ipinle Ogun: Ẹgbẹ Oselu APC ti kede Kudirat Balogun gege bi Igbakeji Gomina
Ẹgbẹ Oselu (All Progressives Congress) ti ìpínlẹ̀ Ogun ti kéde Abileko Kudirat Abiodun Balogun (tí a mọ̀ sí Adegunwa) gẹ́gẹ́…
Read More » -
Ọnarebu Oluṣọla Arikẹ Ayekootọ jawe olubori gẹgẹ bi oludije ADC fun ipo aṣoju-ṣofin agbegbe Alimọṣọ,ipinlẹ Eko
Se ni idunnu n ṣubu layọ fun gbajumọ sọrọsọrọ, to tun jẹ agba oniroyin nni, Ọnarebu Oluṣọla Arikẹ, tọpọ awọn…
Read More » -
Sẹ́nétọ̀ Adeola rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti dìbò fun Aare Tinubu leekeji,ko le pari awon ise ribiribi to n se lowo
Olùdíje sipo gómìnà labe Asia ẹgbẹ Oselu ti (All Progressives Congress) ni Ipinle Ogun, Sẹ́nétọ̀ Solomon Olamilekan Adeola, ti opo…
Read More » -
Seneto Adeola dupe lowo awon oludibo, o seleri eto ijoba to deledoko, o wa ro won ki won jade lati dibo Aare lojo Abameta
Seneto Solomon Olamilekan pelu Iyawo re ati oludije sipo Gomina labe Asia ẹgbẹ Oselu ADC ninu eto idibo odun 2023…
Read More » -
Pẹlu owo tabua to n wọle sapo Eko, Iya ṣi tun n jẹ awọn araalu – Gbadebo Rhodes Vivouṣ
Adijedupo gomina nipinlẹ Eko labẹ asia ẹgbẹ oselu labour party ni ọdun 2023 Gbadebo Rhodes-Vivour ti bu ẹnu atẹ lu…
Read More »