ÒṢÈLÚ

Ko si gomina to se daadaa to gomina Dapo Abiodun- Komuredi .Isa olude

Komuredi Isa olude to je alaga awon osise feyinti nipinle Ogun ti sapejuwe gomina lpinle ogun omooba Dapo Abiodun gege bi gomina to se dara dara ju ni ipinle Ogun.
Komuredi lsa olude soro yi nibi eto isinku oloogbe,  Mama Elisabeti Gbemisola  ljidele  to waye ni ilu Adja Quere ni ijoba ibile Ipobe ni orile ede olominira Benni, lojo kokonla osu kini odun-egbaa-odun-o-le marunlelogun.
Olude ni bi gomina dapo Abiodun se fowosi igbelaruge awon osise ijoba to le ni egberunmerindinlogbon 26,764 ni gbogbo awon apa eka osise ijoba ni ipinle Ogun ti fi han pe gomina kii se odaju eeyan rara.
Bi gomina se fowo si igbelaruge awon osise lenu ise ijoba yi lo tun fi kun owo awon osise feyinti lasiko odun.

Yato siyen gbogbo awon apa eka pata ni gomina ti mu itesiwaju ba lati lgba to ti wa lori aleefa gegebi gomina lpinle ogun.

Olude tesiwaju pe ti a ba n soro awon gomina to se nnkan si gbogbo eka ijoba nipunle ogun gomina DapoAbiodunje okan lara won.

Be ni olude ba awon ebi oloogbe mama  Elisabeth ijidele kedaro mama won, o si wa ro awon obinrin lati ma niwa to dara nile oko.

” Eeyan to n sin olorun daadaa ni mama, won si n fi awon ohun ti won maa n ko nile ijosin huwa,  be ni won tun n fi apeere lele  fawon omo won”.

“Gbogbo awon omo won ni won fiwa jo won agaga onimoero Sunday ijidele. Egbon ko eeyan mora gan- an.”

“Iwaju ti mama dojuko a dara be ni eyin ti won fi sile ko ni baje lase Edumare .”gege bo se so.

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button