Year: 2024
-
ÌṢÒWÒ
Kontirola Muhammed Shuaibu gba Moto,lresi ati awon eru fayawo to po laarin ose kan….o si kilo fawon onifayawo lati fi ipinle ogun sile.
Kontirola Muhammed Shuaibu to Bere ise gege bi oga agba ajo eso asobode nipinle Ogun ni nnkan bi ose kan…
Read More » -
ÌṢÒWÒ
Maa riipe opin de ba ise fayawo ni ipinle ogun-Kontirola Muhammed Shuaibu
Kontirola Muhammed Shuaibu ti je ko di mimo pe oun ma mu opin de ba ise fayawo nipinle Ogun. Shuaibu…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Ope ooo ! Seneto Olamilekan da isokan pada si Yewa- Awori
Isele to sele nibi ayeye ajodun orona to sese pari lojo kini osu kejila odun 2024 yi ti Fi han…
Read More » -
ÀṢÀ ATI ÌṢE
Inu mi ko dun bi awon to sejoba siwaju mi ko se mu idagbasoke ba agbegbe yi….inu mi dun bi won se yi ayeye oronna si oni nitori mi-Gomina Dapo Abiodun
Gomina Dapo Abiodun ti fi aidunnu re han si bi awon to ti sejoba siwaju re nipinle Ogun ko se…
Read More » -
Lobaloba
Ayeye oniberin ti Baale Keesan orile oloye Abodunrin Adeyemi seto re ti fe bere
Baale Keesan orile ni Ariwa Abeokuta, Oloye Waheed Abiodun Abodunrin Adeyemi ti salaye pe gbogbo eto lo ti pari fun…
Read More » -
ÀṢÀ ATI ÌṢE
Nitori ki Gomina ipinle Ogun le wa sibi asekagba Oronna,won yi ayeye ajodun asekagba oronna si ojo isinmi.
Ninu iroyin kan ti oloye Lekan Asuni to je alaga ayeye ajodun oronna fi sita fawon oniroyin loni ojo kerindinlogbon…
Read More » -
ÌṢÒWÒ
Kontirola James ojo ti fa oogun oloro ti won gba lowo awon onifayawo le ajo NDLEA lowo
Kontirola James Ojo to n dari eka akoko ajo eso asobode nipinle Ogun ti fa oogun oloro to le ni…
Read More » -
ÒṢÈLÚ
Aare Bola Tinubu ma a pari opopona Eko si Sokoto ko to di odun 2031-Sen.Adeola Yayi
Seneto Solomon Adeola Olamilekan Yayi ti fi da awon eeyan loju pe ijoba aare Bola Tinubu ma Pari opopona Eko…
Read More »

